Kí Ló Máa Ń Ṣẹlẹ̀ Nínú Gbọ̀ngàn Ìjọba? TẸ̀ Ẹ̣́ Kí Ló Máa Ń Ṣẹlẹ̀ Nínú Gbọ̀ngàn Ìjọba? Wo bó ṣe máa ń rí tá a bá wà nínú Gbọ̀ngàn Ìjọba. Máà bínú, ètò tó o fi ń wo fídíò kò ṣiṣẹ́. Wa Fídíò Yìí Jáde O Tún Lè Wo ÀWỌN Ọ̀NÀ ÌGBỌ́RỌ̀KALẸ̀ TÁ A LÈ LÒ LÓDE Ẹ̀RÍ Ta Ni Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà? Ọ̀pọ̀ èèyàn ló fẹ́ mọ irú ẹni tí àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà jẹ́. Jọ̀wọ́, wo fídíò tí àwa fúnra wa ṣe yìí, kó o lè túbọ̀ mọ̀ wá. ÌBÉÈRÈ TÁWỌN ÈÈYÀN MÁA Ń BÉÈRÈ Kí Ni Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Máa Ń Kọ́ Àwọn Èèyàn? Ìtumọ̀ Bíbélì èyíkéyìí tó bá wù ẹ́ lo lè lò láti fi kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì pẹ̀lú àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà. O sì lè pe gbogbo ìdílé ẹ tàbí kó o pe àwọn ọ̀rẹ́ ẹ wá síbi ìkẹ́kọ̀ọ́ náà. ÌBÉÈRÈ TÁWỌN ÈÈYÀN MÁA Ń BÉÈRÈ Ibo Làwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ti Ń Rówó Tí Wọ́n Ń Ná? A ò kì í gba owó báwọn oníṣọ́ọ̀ṣì ṣe ń gba owó. BÁ A ṢE Ń RAN ARÁ ÌLÚ LỌ́WỌ́ Àǹfààní Wo Ni Gbọ̀ngàn Ìjọba Máa Ṣe Àdúgbò Yín? Gbọ́ ohun táwọn aládùúgbò sọ nípa bó ṣe rí lára wọn pé Gbọ̀ngàn Ìjọba wà ládùúgbò wọn. Nípa Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Lọ sí ìpàdé ìjọ àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Wàá mọ ohun tá a máa ń ṣe láwọn ìpàdé wa, wàá sì mọ ibi tá a ti ń ṣèpàdé tó sún mọ́ ẹ. Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Kí Ló Máa Ń Ṣẹlẹ̀ Nínú Gbọ̀ngàn Ìjọba? ÌPÀDÉ Kí Ló Máa Ń Ṣẹlẹ̀ Nínú Gbọ̀ngàn Ìjọba? Yorùbá Kí Ló Máa Ń Ṣẹlẹ̀ Nínú Gbọ̀ngàn Ìjọba? https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/502014315/univ/art/502014315_univ_sqr_xl.jpg