ÌHÌN RERE LÁTỌ̀DỌ̀ JÉSÙ

Abala 2: “Èyí Ni Ọmọ Mi”

Yorùbá
Abala 2: “Èyí Ni Ọmọ Mi”
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1112023104/univ/art/1112023104_univ_sqr_xl.jpg

ABALA 2

“Èyí Ni Ọmọ Mi”

“Èyí Ni Ọmọ Mi”

(Bó ṣe gùn tó: 52:46)

Jòhánù Arinibọmi kéde pé Mèsáyà tí Ọlọ́run ṣèlérí ti dé. Jésù bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òjíṣẹ́ rẹ̀. Àwọn ohun tó wà nínú abala yìí rèé: