Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

JW LIBRARY

Ìrànlọ́wọ́ Lórí Windows

Ìrànlọ́wọ́ Lórí Windows

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà la ṣe ètò ìṣiṣẹ́ JW Library. Oríṣiríṣi ìtumọ̀ Bíbélì ló wà lórí ẹ̀, tó fi mọ́ àwọn ìwé ńlá àtàwọn ìwé pẹlẹbẹ tá a fi ń kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì.

 

 

Ohun Tuntun

October 2021 (Version 12.5)

  • Wàá lè wa Ìwé Ìwádìí tuntun jáde lábẹ́ abala ìwádìí nínú Bíbélì

  • ÀKÍYÈSÍ: Version 12.5 ni ètò ìṣiṣẹ́ JW Library tó máa Windows 10 versions 1709, 1803 àti 1809 ṣiṣẹ́ kẹ́yìn. Tó bá jẹ́ àwọn Windows tó ti pẹ́ yìí ni ẹ̀rọ rẹ ń lò, ó máa nílò láti jẹ́ kí Windows yẹn gbé pẹ́ẹ́lí sí i kó o lè rí àwọn ohun tuntun tó máa jáde lórí JW Library lọ́jọ́ iwájú wà jáde.

July 2021 (Version 12.4)

  • O ti lè yan èdè tó o fẹ́ kí Ìròyìn Tuntun máa jẹ́.

  • O lè fi ìlujá sí Ẹsẹ Ojúmọ́ àti Ìpàdé ráńṣẹ́ sí àwọn míì.

  • Ó ti wá túbọ̀ rọrùn láti rí ìsọfúnni nípa àwọn ìtẹ̀jáde tá a ti ṣe àtúnṣe sí.

January 2021 (Version 12.3)

  • A ti ṣe àtúnṣe sí bí a ṣe kọ àwọn lẹ́tà kó lè túbọ̀ rọrùn láti kà, kó sì rí bó ṣe rí lórí ìkànnì jw.org.

 

NÍ APÁ YÌÍ

Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Lo JW Library​—Windows

Learn how to use the main features of JW Library on Windows devices.

Bó O Ṣe Lè Wa Bíbélì Jáde Kó O sì Máa Lò Ó​—Windows

Kọ́ bó o ṣe lè wa Bíbélì jáde lórí JW Library, kó o sì máa lò ó lórí àwọn fóònù Windows.

Bó O Ṣe Lè Wa Ìwé Jáde Kó O sì Máa Lò Ó​—Lórí Windows

Kọ́ bó o ṣe lè wa ìwé jáde lórí JW Library, kó o sì máa lò ó lórí àwọn fóònù Windows.

Bó O Ṣe Lè Sàmì sí Ìwé​—Lórí Windows

Kọ́ bó o ṣe lè máa sàmì sí ìwé nínú JW Library lórí àwọn fóònù Windows.

Wo Àwọn Ohun Tó O Ti Kà Tẹ́lẹ̀​—Lórí Windows

Kọ́ bó o ṣe lè wo àwọn ohun tó o ti kà tẹ́lẹ̀ nínú JW Library lórí àwọn fóònù Windows.

Pinnu Bó O Ṣe Fẹ́ Kí Ìwé Tó Ò Ń Kà Rí​—Lórí Windows

Kọ́ bó o ṣe lè ṣe é kí ìwé tó ò ń kà nínú JW Library rí bó o ṣe fẹ́ kó rí lórí àwọn fóònù Windows.

Wá Ọ̀rọ̀ Nínú Bíbélì Tàbí Nínú Ìwé​—Lórí Windows

Kọ́ bó o ṣe lè wá ọ̀rọ̀ nínú Bíbélì tàbí ìwé, kó o sì tún wá àkòrí ọ̀rọ̀ ní Insight on the Scriptures nínú JW Library lórí àwọn fóònù Windows.

Bó O Ṣe Lè Kun Ọ̀rọ̀​—Lórí Windows

Kọ́ bó o ṣe lè kun ọ̀rọ̀ nínú JW Library lórí àwọn fóònù Windows.

Àwọn Ìbéèrè Táwọn Èèyàn Máa Ń Béèrè​—JW Library (Lórí Windows)

Wá ìdáhùn sí àwọn ìbéèrè táwọn èèyàn sábà máa ń béèrè.