Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

JW LIBRARY

Ìrànlọ́wọ́ Lórí iPad, iPhone àti iPod touch

Ìrànlọ́wọ́ Lórí iPad, iPhone àti iPod touch

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà la ṣe ètò ìṣiṣẹ́ JW Library. Oríṣiríṣi ìtumọ̀ Bíbélì ló wà lórí ẹ̀, tó fi mọ́ àwọn ìwé ńlá àtàwọn ìwé pẹlẹbẹ tá a fi ń kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì.

 

 

Ohun Tuntun Tó Wà ní Version 10.0

  • Wàá rí Bíbélì New World Translation of the Holy Scriptures (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)

  • Wàá rí àtẹ́tísí àwọn ọ̀rọ̀ tó wà níbi àwọn àwòrán Study Bible

  • Wàá rí àbá látinú Glossary and Research Guide nígbà tó o bá ń wá ọ̀rọ̀, láfikún sí tàwọn àbá inú ìwé Insight

 

NÍ APÁ YÌÍ

Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Lo JW Library​—Lórí iOS

Kọ́ bó o ṣe lè lo àwọn apá pàtàkì nínú ètò ìṣiṣẹ́ JW Library lórí àwọn fóònù iOS.

Bó O Ṣe Lè Wa Bíbélì Jáde Kó O sì Máa Lò Ó​—Lórí iOS

Kọ́ bó o ṣe lè wa Bíbélì jáde lórí JW Library, kó o sì máa lò ó lórí àwọn fóònù iOS.

Bó O Ṣe Lè Wa Ìwé Jáde Kó O sì Máa Lò Ó​—Lórí iOS

Kọ́ bó o ṣe lè wa ìwé jáde lórí JW Library, kó o sì máa lò ó lórí àwọn fóònù iOS.

Bó O Ṣe Lè Sàmì sí Ìwé​—Lórí iOS

Kọ́ bó o ṣe lè wa ìwé jáde lórí JW Library, kó o sì máa lò ó lórí àwọn fóònù iOS.

Wo Àwọn Ohun Tó O Ti Kà Tẹ́lẹ̀​—Lórí iOS

Kọ́ bó o ṣe lè wo àwọn ohun tó o ti kà tẹ́lẹ̀ nínú JW Library lórí àwọn fóònù iOS.

Pinnu Bó O Ṣe Fẹ́ Kí Ìwé Tó Ò Ń Kà Rí​—Lórí iOS

Kọ́ bó o ṣe lè ṣe é kí ìwé tó ò ń kà nínú JW Library rí bó o ṣe fẹ́ kó rí lórí àwọn fóònù iOS.

Bó O Ṣe Lè Kun Ọ̀rọ̀​—Lórí iOS

Kọ́ bó o ṣe lè kun ọ̀rọ̀ nínú JW Library lórí àwọn fóònù iOS.

Bó O Ṣe Lè Kun Ọ̀rọ̀​—Lórí iOS

Kọ́ bó o ṣe lè kun ọ̀rọ̀ nínú JW Library lórí àwọn fóònù iOS.

Àwọn Ìbéèrè Táwọn Èèyàn Máa Ń Béèrè​—JW Library (lórí iOS)

Wá ìdáhùn sí àwọn ìbéèrè táwọn èèyàn sábà máa ń béèrè.