Yorùbá
Káàdì Èèyàn Inú Bíbélì
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1011235/univ/art/1011235_univ_sqr_xl.jpg

Káàdì Eré Bíbélì

Kẹ́kọ̀ọ́ nípa àwọn èèyàn tó o fẹ́ràn nínú Bíbélì. Wa káàdì kọ̀ọ̀kan jáde, tẹ̀ ẹ́, ká a sí méjì kó o sì tọ́jú rẹ̀. Ní gbogbo wọn lọ́wọ́!