KÁÀDÌ NÍPA ẸNÌ KAN NÍNÚ BÍBÉLÌ Pọ́ọ̀lù TẸ̀ Ẹ̣́ Wa káàdì yìí jáde, kó o sì kẹ́kọ̀ọ́ nípa Pọ́ọ̀lù. Gé e, ká a sí méjì kó o sì tọ́jú rẹ̀. Àwọn Àkòrí Tó Jọ Ọ́ Káàdì Eré Bíbélì O Tún Lè Wo KÁÀDÌ ERÉ BÍBÉLÌ Káàdì Eré Bíbélì Nípa Tímótì Tímótì yàn láti sin Ọlọ́run nígbà tó wà lọ́mọdé. Àwọn ọ̀nà wo lo lè gbà dà bí Tímótì? KỌ́ ỌMỌ RẸ Onígboyà Ni Mọ̀lẹ́bí Pọ́ọ̀lù Ọ̀dọ́kùnrin yìí gba ẹ̀mí mọ̀lẹ́bí rẹ̀ là. Kí ló ṣe? Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere. Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Pọ́ọ̀lù KÁÀDÌ ERÉ BÍBÉLÌ Káàdì Eré Bíbélì Nípa Pọ́ọ̀lù Yorùbá Káàdì Eré Bíbélì Nípa Pọ́ọ̀lù https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/502012436/univ/art/502012436_univ_sqr_xl.jpg