Tọ́kì
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní Orílẹ̀-èdè Turkey
-
Iye àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà—4,615
-
Iye àwọn ìjọ—59
-
Iye àwọn tó wá síbi Ìrántí Ikú Kristi—7,447
-
Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún—19,716
-
Iye èèyàn—85,665,000
Ilé Ẹjọ́ Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn ti Ilẹ̀ Yúróòpù Sọ Pé Ìjọba Orílẹ̀-èdè Turkey Gbọ́dọ̀ Fọwọ́ Sí I Pé “Ibi Ìjọsìn” Ni Gbọ̀ngàn Ìjọba
Bó tiẹ̀ jẹ́ pé ìṣòro táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń ní lábẹ́ òfin lórílẹ̀-èdè Turkey ti ń lójú díẹ̀díẹ̀, wọn ò tíì lè ní ilé ìjọsìn tiwọn tàbí kí wọ́n kọ́ ọ torí wọ́n ń ṣe ẹ̀tanú sí wọn.

