Taiwan
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní Taiwan
-
Iye Àwọn Elẹ́rìí Jèhófà—11,924
-
Iye Ìjọ—179
-
Iye àwọn tó wá síbi Ìrántí Ikú Kristi—20,549
-
Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí kan máa wàásù fún—1,982
-
Iye èèyàn—23,396,000
Ètò Iṣẹ́ Àṣesìnlú Yọrí sí Rere Lórílẹ̀-èdè Taiwan
Ìjọba orílẹ̀-èdè Taiwan ṣètò pé káwọn tí ẹ̀rí ọkàn ò jẹ́ kí wọ́n ṣiṣẹ́ ológun máa ṣiṣẹ́ àṣesìnlú ní àfidípò sí iṣẹ́ ológun.

