ÌRÒYÌN

Bọ̀géríà

Yorùbá
Bọ̀géríà
/assets/ct/fa815d8e9f/images/syn_placeholder_sqr.png

Bọ̀géríà

 

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní Orílẹ̀-èdè Bọ̀géríà

  • Iye àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà​—3,040

  • Iye àwọn ìjọ​—58

  • Iye àwọn tó wá síbi Ìrántí Ikú Kristi​—6,371

  • Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún​—2,152

  • Iye èèyàn​—6,437,000

2017-04-07

BỌ̀GÉRÍÀ

Ṣé Àwọn Ilé Ẹjọ́ ní Bọ̀géríà Máa Fọwọ́ sí I Pé Àwọn Aráàlú Lómìnira Ẹ̀sìn?

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó wà ní Bọ̀géríà ti ń gbé ìgbésẹ̀ láti pe ẹjọ́ lórí àwọn aláṣẹ ìlú 44 tí wọ́n ṣòfin láti fi ẹ̀tọ́ táwọn Ẹlẹ́rìí ní láti sọ ohun tí wọ́n gbà gbọ́ dù wọ́n.

2016-10-06

BỌ̀GÉRÍÀ

Àjọ Kan Lábẹ́ Ìjọba Orílẹ̀-èdè Bọ̀géríà Fìyà Jẹ Àwọn Tó Ń Ṣe Ẹ̀tanú Ẹ̀sìn

Ìjọba ti bu owó ìtanràn gọbọi lé iléeṣẹ́ SKAT TV ní Bọ̀géríà àtàwọn oníròyìn wọn méjì torí wọ́n ṣe àwọn ètò kan tó mú káwọn èèyàn kórìíra àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà, kí wọ́n sì máa hùwà ipá sí wọn.