AGBÈGBÈ KỌ̀Ọ̀KAN

Azerbaijan

Yorùbá
Azerbaijan
/assets/ct/fa815d8e9f/images/syn_placeholder_sqr.png

Azerbaijan

 

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní Orílẹ̀-èdè Azerbaijan

  • Iye àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà​—1,824

  • Iye àwọn ìjọ​—24

  • Iye àwọn tó wá síbi Ìrántí Ikú Kristi​—3,783

  • Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún​—5,725

  • Iye èèyàn​—10,225,000

  • Àwọn Ẹlẹ́rìí tí Wọ́n Fi Sẹ́wọ̀n Torí Ohun tí Wọ́n Gbà Gbọ́​—0

2018-04-23

AZERBAIJAN

Ilé Ẹjọ́ Lórílẹ̀-èdè Azerbaijan Ní Kí Wọ́n Sanwó Gbà-máà-bínú fún Irina Zakharchenko àti Valida Jabrayilova

Ilé ẹjọ́ kan nílùú Baku ní Azerbaijan sọ pé kí wọ́n sanwó gbà-máà-bínú fún àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà méjì táwọn aláṣẹ fi sẹ́wọ̀n láìtọ́ fún oṣù mọ́kànlá.

2017-06-12

AZERBAIJAN

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ní Káwọn Aláṣẹ ní Azerbaijan Dá Àwọn tí Wọ́n Tì Mọ́lé Láìṣẹ̀ Sílẹ̀

Ṣe ni wọ́n ń fìyà jẹ Irina Zakharchenko àti Valida Jabrayilova bíi pé ọ̀daràn paraku ni wọ́n, torí pé wọ́n ń sọ ohun tí wọ́n gbà gbọ́ fáwọn míì. Ìjọba Azerbaijan sì ti sọ pé àwọn ò ní ṣe ẹ̀tanú ẹ̀sìn. Ṣé wọ́n máa wá kó ọ̀rọ̀ wọn jẹ ni?