IṢẸ́ ÌJỌSÌN ÌDÍLÉ Kórà Ṣọ̀tẹ̀ NÚMÉRÌ ORÍ 16 ÀTI 17 Ìtọ́ni fún Àwọn Òbí: Kí ìdílé rẹ fi àwọn nǹkan yìí kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì pa pọ̀. Wà á jáde Kórà Ṣọ̀tẹ̀ IṢẸ́ ÌJỌSÌN ÌDÍLÉ Kórà Ṣọ̀tẹ̀ NÚMÉRÌ ORÍ 16 ÀTI 17 Ìtọ́ni fún Àwọn Òbí: Kí ìdílé rẹ fi àwọn nǹkan yìí kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì pa pọ̀. Wà á jáde Kórà Ṣọ̀tẹ̀ Àwọn Àkòrí Tó Jọ Ọ́ Iṣẹ́ Ìjọsìn Ìdílé O Tún Lè Wo KÁÀDÌ ERÉ BÍBÉLÌ Káàdì Bíbélì Nípa Kórà A lè kọ́ ẹ̀kọ́ pàtàkì látinú àṣìṣe rẹ̀. ÀWỌN ÀWÒRÁN ÌTÀN BÍBÉLÌ Kórà Ṣọ̀tẹ̀ Se Mose ati Aaroni ni Kora sote si abi Olorun? ERÉ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ FÚN ÀWỌN ỌMỌDÉ Àgọ́ Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Gé àwòrán àgọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì jáde, tò ó, kó o sì fi sọ ìtàn ohun tó ṣẹlẹ̀ sí Kórà. Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.