Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

ÀWỌN ÀWÒRÁN ÌTÀN BÍBÉLÌ

Kórà Ṣọ̀tẹ̀

Kí ló ṣẹlẹ̀ sí Kórà nígbà tó ṣọ̀tẹ̀ sí Mósè àti Áárónì nínú aginjù? Ka àwòrán ìtàn Bíbélì tó wà lórí ìkànnì tàbí kó o tẹ̀ ẹ́ jáde.