Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwọn Tó Túmọ̀ Bíbélì

Wọ́n Mọyì Bíbélì​—Díẹ̀ Nínú Ìtàn William Tyndale

Àwọn iṣẹ́ tó ṣe fi hàn pé ó nífẹ̀ẹ́ Bíbélì, a sì ń jàǹfààní látinú ẹ̀ títí dòní.

Wọ́n Mọyì Bíbélì

William Tyndale àti Michael Servetus jẹ́ méjì lára àwọn tó fi èmí ara wọn wewu, tí wọn ò sì fi iyì ara wọn láwùjọ pè kí wọ́n lè kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì láìka àtakò àti ìhalẹ̀mọ́ni sí.

Àwọn Atúmọ̀ Èdè Méjì Dá Orúkọ Ọlọ́run Pa Dà Sínú Májẹ̀mú Tuntun

Kí nìdí tó fi yẹ kí wọ́n dá orúkọ Ọlọ́run pa dà? Ǹjẹ́ ó tiẹ̀ pọn dandan kí wọ́n ṣe bẹ́ẹ̀?

Bí Huldrych Zwingli Ṣe Wá Òtítọ́ Bíbélì

Ní ọgọ́rùn-ún ọdún kẹrìndínlógún, Zwingli rí ọ̀pọ̀ òtítọ́ inú Bíbélì, ó sì jẹ́ káwọn èèyàn mọ òtítọ́ yìí. Kí la lè kọ́ nínú bó ṣe lo ìgbésí ayé rẹ̀ àti ohun tó gbà gbọ́?

Desiderius Erasmus

Wọ́n ní “a lè fi wé àwọn èèyàn tí wọ́n jẹ́ ìlúmọ̀ọ́ká lóde òní.” Kí ló mú káwọn èèyàn mọ̀ ọ́n nílé lóko?

Bíbélì Bedell—Bíbélì Tó Mú Káwọn Èèyàn Túbọ̀ Lóye Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run

Ọgọ́rùn-ún mẹ́ta ọdún ni kò fi sí ìtumọ̀ Bíbélì mí ì ní èdè Irish.

Elias Hutter Ṣiṣẹ́ Ribiribi Sínú Àwọn Bíbélì Èdè Hébérù Tó Ṣe

Elias Hutter, tó jẹ́ ọ̀mọ̀wé kan ní ọgọ́rùn-⁠ún ọdún kẹrìndínlógún tẹ Bíbélì èdè Hébérù méjì tó ṣàrà ọ̀tọ̀ jáde.