Ohun Tuntun Wo Ló Wà ní JW.ORG?
ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
Àwọn Tí Bíbélì Sọ̀rọ̀ Wọn: Mánáénì Fi Ìjọsìn Jèhófà Ṣáájú Láyé Ẹ̀
Wàá rí bí Mánáénì ṣe fi ìjọsìn Jèhófà ṣáájú ohun táyé kà sí pàtàkì.
ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
May 2026
Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti July 6–August 9, 2026 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
Peter Hamadej: Jèhófà Jẹ́ Kí N Ṣe Ìpinnu Tó Dáa
Arákùnrin Peter àti Lenka ìyàwó ẹ̀ kojú àwọn ìṣòro kan. Àmọ́ Jèhófà ràn wọ́n lọ́wọ́ láti ṣe ìpinnu tó dáa láwọn ìgbà tí nǹkan ò rọrùn.
TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?
Bí Ẹranko Tí Wọ́n Ń Pè ní Beaver Ṣe Máa Ń Kọ́ Ìsédò—Ta Ló Ṣiṣẹ́ Àrà Yìí?
Kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìdí táwọn kan fi máa ń pe ẹranko tá a mọ̀ sí beaver yìí ní ẹnjiníà tó ta yọ.
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Aago Doomsday Ti Túbọ̀ Sún Mọ́ Ọ̀gànjọ́ Òru
Aago Doomsday ti tubo sun mo aago mejila oganjo oru ju ti igbakigba ri lo. Ka apileko yii ko o le mo ohun ti Bibeli so nipa ojo ola ati ohun to maa je kokan e bale.
ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ
Wọ́n Fi Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Sẹ́wọ̀n Torí Ohun Tí Wọ́n Gbà Gbọ́ Láwọn Orílẹ̀-Èdè Kan
Àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n ti fi àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà sẹ́wọ̀n torí pé à ń lo ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn tá a ní lábẹ́ òfin àti torí ohun tá a gbà gbọ́. Nǹkan máa ń nira gan-an fáwọn ará wa kan tí wọ́n fi sẹ́wọ̀n.
KẸ́KỌ̀Ọ́ LÁRA JÉSÙ
“Ẹ Máa Gbọ́ Nípa Àwọn Ogun”
Ka àpilẹ̀kọ yìí kó o lè mọ ìtumọ̀ ọ̀rọ̀ tí Jésù sọ yìí.
ÀKÓJỌ ÀPILẸ̀KỌ ÀTI FÍDÍÒ
Ìrànlọ́wọ́ fún Àwọn Tí Ò Ríran
Ka àpilẹ̀kọ yìí kó o lè rí bí àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ṣe ń jẹ́ káwọn tí kò ríran àtàwọn tí ò ríran dáadáa mọ̀ nípa àwọn ohun rere tí Bíbélì sọ nípa ọjọ́ ọ̀la.
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Ìkànnì Àjọlò Ń Ṣàkóbá Fáwọn Ọ̀dọ́ Kárí Ayé
Imoran to daa wa ninu Bibeli to le ran awon obi lowo lati daabo bo awon omo won lowo ewu to wa ninu ikanni ajolo.

