Ìròyìn

 

2026-02-09

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2026 #1

Nínú ìròyìn yìí, a máa sọ̀rọ̀ nípa ìtọ́ni tuntun tá a máa tẹ̀ lé tá a bá ń fi ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé! kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́.

2026-01-02

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2025 #8

Nínú ìròyìn yìí, a sọ̀rọ̀ nípa bí àwọn fídíò Ìhìn Rere Látọ̀dọ̀ Jésù ṣe ń wọ àwọn ará wa lọ́kàn, tó sì ń mú kí ọ̀pọ̀ nífẹ̀ẹ́ sí òtítọ́.

2025-11-19

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2025 #7

Nínú ìròyìn yìí, a máa sọ̀rọ̀ nípa àwọn nǹkan amóríyá tó ṣẹlẹ̀ ní Ọdún Iṣẹ́ Ìsìn 2025 àti bí Jèhófà ṣe bù kún iṣẹ́ tá a ṣe kárí ayé.

2026-01-02

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2025 #6

Nínú ìròyìn yìí, a máa sọ̀rọ̀ nípa ẹsẹ Ìwé Mímọ́ ọdún 2026, a sì máa mú orin tuntun kan jáde.

2025-09-01

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2025 #5

Nínú ìròyìn yìí, a máa sọ̀rọ̀ nípa àwọn ìlànà Bíbélì tó máa ràn wá lọ́wọ́ láti ṣèpinnu tó bọ́gbọ́n mu lórí ọ̀rọ̀ àfikún ẹ̀kọ́.

2025-07-11

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2025 #4

Nínú ìròyìn yìí, a máa sọ̀rọ̀ nípa àwọn ìlànà Bíbélì tó máa ràn wá lọ́wọ́ ká lè ṣe ìpinnu tó bọ́gbọ́n mu tó bá dọ̀rọ̀ àwọn àṣà ìbílẹ̀ kan àti lílo àwọn àmì tàbí àwòrán kan.

2025-07-11

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2025 #3

Nínú ìròyìn yìí, a máa sọ̀rọ̀ nípa ohun tá a lè ṣe tó máa jẹ́ ká lè ṣe púpọ̀ sí i lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn Jèhófà láwọn oṣù tó ń bọ̀.

2025-04-09

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2025 #2

Nínú ìròyìn yìí, a sọ̀rọ̀ nípa àwọn nǹkan tá à ń ṣe ká lè kọ́ àwọn ará kí wọ́n lè kàwé dáadáa, àti bí ẹbọ ìràpadà Jésù ṣe mú kí ọkàn wa balẹ̀. A tún sọ̀rọ̀ nípa orin tuntun tá a máa kọ ní àpéjọ agbègbè tọdún 2025.

2025-03-27

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2025 #1

Nínú ìròyìn yìí, a máa rí bá a ṣe lè lo apá “Ohun Tá À Ń Kọ́ Àwọn Èèyàn” tó wà ní àfikún A nínú ìwé Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Èèyàn—Máa Sọ Wọ́n Dọmọ Ẹ̀yìn. Apá yìí máa jẹ́ ká lè bá àwọn èèyàn sọ̀rọ̀ lóde ìwàásù, ká sì gbádùn ẹ̀.

Wọ́n Fi Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Sẹ́wọ̀n Torí Ohun Tí Wọ́n Gbà Gbọ́ Láwọn Orílẹ̀-Èdè Kan

Àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n ti fi àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà sẹ́wọ̀n torí pé à ń lo ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn tá a ní lábẹ́ òfin àti torí ohun tá a gbà gbọ́. Nǹkan máa ń nira gan-an fáwọn ará wa kan tí wọ́n fi sẹ́wọ̀n.