Yorùbá
Palestinian Territories
/assets/ct/28ada02fb0/images/syn_placeholder_sqr.png

Palestinian Territories

 

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní Ilẹ̀ Palẹ́sínì

  • Iye àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà​—81

  • Iye àwọn ìjọ​—2

  • Iye àwọn tó wá síbi Ìrántí Ikú Kristi​—204

  • Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún​—71,813

  • Iye èèyàn​—5,745,000

2016-09-27

PALESTINIAN TERRITORIES

Wọ́n Ń Fi Ẹ̀tọ́ Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Tó Wà ní Àgbègbè Palẹ́sínì Dù Wọ́n

Wọn ò gbà láti forúkọ ẹ̀sìn àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà sílẹ̀ lábẹ́ òfin torí wọn ò ka ẹ̀sìn wọn sí, ìyẹn wá ń jẹ́ kí wọ́n máa fi ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn tí wọ́n ní dù wọ́n, kò sì yẹ kó rí bẹ́ẹ̀.