ÌRÒYÌN

Uzbekistan

Yorùbá
Uzbekistan
/assets/ct/b4d7e1101e/images/syn_placeholder_sqr.png

Uzbekistan

 

2019-03-19

UZBEKISTAN

Àwọn Ilé Ẹjọ́ Gíga ní Uzbekistan Dájọ́ Pé Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Lẹ́tọ̀ọ́ Láti Ní Àwọn Ìwé Tó Dá Lórí Bíbélì

Lẹ́nu àìpẹ́ yìí, ilé ẹjọ́ gíga dá àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà láre pé wọn ò jẹ̀bi ẹjọ́ tí wọ́n dá wọn lẹ́bi rẹ̀ tẹ́lẹ̀, wọn ò sì ní sanwó ìtanràn mọ́.