Tajikistan Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní Tajikistan Àwọn Ẹlẹ́rìí tí Wọ́n Fi Sẹ́wọ̀n Torí Ohun tí Wọ́n Gbà Gbọ́—0 Wọ́n Fi Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Sẹ́wọ̀n Torí Ohun Tí Wọ́n Gbà Gbọ́ Láwọn Orílẹ̀-Èdè Kan 2020-04-21 TAJIKISTAN Wọ́n Fi Arákùnrin Jovidon Bobojonov Sẹ́wọ̀n Ọdún Méjì Lórílẹ̀-èdè Tajikistan 2020-05-20 TAJIKISTAN Àwọn Aláṣẹ Ìlú Tajik Ju Arákùnrin Shamil Khakimov, Ẹni Ọdún Méjìdínláàádọ́rin (68) Sẹ́wọ̀n Ọdún Méje Àtààbọ̀ Lọ́nà Tí Kò Tọ́