KÁÀDÌ NÍPA ÈÈYÀN INÚ BÍBÉLÌ Sámúsìnì TẸ̀ Ẹ̣́ Wa káàdì yìí jáde, kó o sì kẹ́kọ̀ọ́ nípa Sámúsìnì. Gé e, ká a sí méjì kó o sì tọ́jú rẹ̀. Àwọn Àkòrí Tó Jọ Ọ́ Káàdì Eré Bíbélì O Tún Lè Wo KÁÀDÌ ERÉ BÍBÉLÌ Káàdì Bíbélì Mánóà Òun ni bàbá ọ̀kan lára àwọn tó lágbára jù lọ tó tíì gbé láyé. ÀWỌN ÀWÒRÁN ÌTÀN BÍBÉLÌ Ẹ̀mí Mímọ́ fún Sámúsìnì Lágbára Gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan lára àwọn onídàájọ́ Ísírẹ́lì Sámúsìnì ṣe àwọn ohun àgbàyanu. Báwo ni ẹ̀mí mímọ́ Jèhófà ṣe ràn án lọ́wọ́? Báwo lo ṣe lè gba ẹ̀mí mímọ́ Ọlọ́run? ERÉ ALÁWÒRÁN Jèhófà Fún Sámúsìnì ní Ẹ̀mí Mímọ́ Eré yìí máa ran àwọn ọmọdé tọ́jọ́ orí wọ́n jẹ́ mẹ́ta sí mẹ́fà lọ́wọ́ láti mọ nípa Sámúsìnì àti agbára rẹ̀. IṢẸ́ ÌJỌSÌN ÌDÍLÉ Bí Ẹ̀mí Mímọ́ Ṣe Máa Ń Fún Wa Lágbára Ká Lè Sin Jèhófà Lo eré yìí láti kọ́ ọmọ rẹ nípa bí Jèhófà ṣe máa ń lo ẹ̀mí mímọ́ rẹ̀ láti fún wa lágbára. Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere. Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Sámúsìnì KÁÀDÌ ERÉ BÍBÉLÌ Káàdì Bíbélì Nípa Sámúsìnì Yorùbá Káàdì Bíbélì Nípa Sámúsìnì https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/502012441/univ/art/502012441_univ_sqr_xl.jpg