ERÉ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ Àwọn Ànímọ́ Tí Ẹ̀mí Mímọ́ Máa Ń Mú Ká Ní TẸ̀ Ẹ̣́ Kọ́ nípa àwọn ànímọ́ mẹ́sàn-án tí ẹ̀mí mímọ́ Ọlọ́run máa ń mú ká ní. Wà á jáde Àwọn Àkòrí Tó Jọ Ọ́ Eré Ìkẹ́kọ̀ọ́ O Tún Lè Wo ÀWỌN ÀWÒRÁN ÌTÀN BÍBÉLÌ Ẹ̀mí Mímọ́ fún Sámúsìnì Lágbára Gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan lára àwọn onídàájọ́ Ísírẹ́lì Sámúsìnì ṣe àwọn ohun àgbàyanu. Báwo ni ẹ̀mí mímọ́ Jèhófà ṣe ràn án lọ́wọ́? Báwo lo ṣe lè gba ẹ̀mí mímọ́ Ọlọ́run? ERÉ ALÁWÒRÁN Máa Gbàdúrà Kí Ọlọ́run Fún Ẹ Ní Ẹ̀mí Mímọ́ Eré yìí máa ran àwọn ọmọdé tọ́jọ́ orí wọn jẹ́ mẹ́fà sí mẹ́jọ lọ́wọ́ láti mọ ìdí tó fi yẹ kí wọ́n máa gbàdúrà. ERÉ ALÁWÒRÁN Jèhófà Fún Sámúsìnì ní Ẹ̀mí Mímọ́ Eré yìí máa ran àwọn ọmọdé tọ́jọ́ orí wọ́n jẹ́ mẹ́ta sí mẹ́fà lọ́wọ́ láti mọ nípa Sámúsìnì àti agbára rẹ̀. KÁÀDÌ ERÉ BÍBÉLÌ Káàdì Bíbélì Nípa Sámúsìnì Wo ohun tó mú kí Sámúsìnì lágbára gan-an. IṢẸ́ ÌJỌSÌN ÌDÍLÉ Bí Ẹ̀mí Mímọ́ Ṣe Máa Ń Fún Wa Lágbára Ká Lè Sin Jèhófà Lo eré yìí láti kọ́ ọmọ rẹ nípa bí Jèhófà ṣe máa ń lo ẹ̀mí mímọ́ rẹ̀ láti fún wa lágbára. Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.