ERÉ ALÁWÒRÁN Dáfídì Wá ní Orúkọ Ọlọ́run TẸ̀ Ẹ̣́ To àwọn lẹ́tà inú orúkọ Ọlọ́run, kó o wá kọ́ ohun tí orúkọ rẹ̀ túmọ̀ sí. Wà á jáde Àwọn Àkòrí Tó Jọ Ọ́ Eré Aláwòrán O Tún Lè Wo KÁÀDÌ ERÉ BÍBÉLÌ Káàdì Eré Bíbélì Nípa Dáfídì Ó ṣeé ṣe kó o mọ ìtàn Dáfídì àti Gòláyátì, àmọ́ ọ̀pọ̀ nǹkan ló ṣì yẹ kó o mọ̀ nípa Dáfídì. ERÉ ALÁWÒRÁN Jèhófà Máa Ń Rí Ọkàn Wa eré yìí jáde, kun àwòrán rẹ̀, ki o sì kọ́ àwọn ìwà táá jẹ́ kó o lẹ́wà lójú Ọlọ́run. IṢẸ́ ÌJỌSÌN ÌDÍLÉ Jíjẹ́ Onígboyà Kọ́ àwọn ọmọ rẹ ní ohun tó máa ń mú kéèyàn nígboyà. ÀWỌN ÀWÒRÁN ÌTÀN BÍBÉLÌ Dáfídì Jẹ́ Onígboyà Kí ló mú kí Dáfídì gbà pá òun lè ṣẹ́gun Gòláyátì? Kí ló sì lè mú kó o nígboyà láti ṣe ohun tó tọ́? KỌ́ ỌMỌ RẸ Dáfídì Kò Bẹ̀rù Ka ìtàn inú Bíbélì tó dùn yìí kó o lè mọ ohun tó mú kí Dáfídì nígboyà tó bẹ́ẹ̀. Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.