Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Fífẹ́ra Sọ́nà

Ṣó Ti Yẹ Kí N Lẹ́ni Tí Mò Ń Fẹ́?

Ohun márùn-ún tó máa jẹ́ kó o mọ̀ bóyá o ti ṣe tán láti lẹ́ni tí wàá máa fẹ́, tó o sì lè bá ṣègbéyàwó.

Ṣé Ó Burú Kéèyàn Máa Tage?

Kí ló túmọ̀ sí gan-an kéèyàn máa tage? Kí ló máa ń mú káwọn kan ṣe bẹ́ẹ̀? Ṣé ó tiẹ̀ léwu?

Ṣé Ọ̀rẹ́ Lásán Ni Wá àbí Ọ̀rọ̀ Ìfẹ́ Ti Wọ̀ Ọ́?—Apá 1: Báwo Ni Ẹni Yìí Ṣe Ń Ṣe sí Mi?

Wo àwọn ohun tó o lè ṣe kó o lè mọ̀ bóyá bí ẹnì kan ṣe ń ṣe sí ẹ fi hàn pé ó fẹ́ kẹ́ ẹ máa fẹ́ra àbí ó kàn fẹ́ kẹ́ ẹ jẹ́ ọ̀rẹ́.

Ṣé Ọ̀rẹ́ Lásán Ni Wá àbí Ọ̀rọ̀ Ìfẹ́ Ti Wọ̀ Ọ́?—Apá 2: Báwo Ní Mo Ṣe Ń Ṣe sí Ẹni Yìí?

Ṣé kì í ṣe pé ọ̀rẹ́ rẹ ti ń wò ó pé o fẹ́ kí ẹ máa fẹ́ra? Wo àwọn àbá yìí.

Kí Ló Yẹ Kí N Fi Sọ́kàn Tí Mo Bá Ń Fẹ́ Ẹnì Kan Sọ́nà?

Ohun mẹ́ta tó yẹ kó o fi sọ́kàn tó o bá ń fẹ́ ẹnì kan sọ́nà

Ṣé Ìfẹ́ Tòótọ́ Ni àbí Ìfẹ́ Ojú Lásán?

Mọ ìyàtọ̀ tó wà láàárín ìfẹ́ ojú lásán àti ìfẹ́ tòótọ́.

Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Gbígbé Pọ̀ Láìṣègbéyàwó?

Àwọn ìtọ́ni Ọlọ́run jẹ́ ká mọ bá a ṣe lè ní ìdílé aláyọ̀, kò sì ìgbà tí ìlànà rẹ̀ kì í ṣe àwọn tó bá ń tẹ̀ lé e láǹfààní.

Ṣé Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ní Òfin tí Wọ́n Máa Ń Tẹ̀ Lé tí Wọ́n Bá Ń Fẹ́ra Sọ́nà?

Ṣe eré ìnàjú lásán làwọn tó ń fẹ́ra sọ́nà ń bára wọn ṣe àbí ó jù bẹ́ẹ̀ lọ?

Kí Ni Ìfẹ́ Tòótọ́?

Ìlànà Bíbélì lè ràn wá lọ́wọ́ láti yan ọkọ tàbí aya rere, ó sì lè jẹ́ kí tọkọtaya máa fìfẹ́ tòótọ́ hàn sí ara wọn.

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Bọ́ Lọ́wọ́ Ẹ̀dùn Ọkàn Tá Ò Bá Fẹ́ra Wa Mọ́?

Wo bó o ṣe lè bọ́ lọ́wọ́ ẹ̀dùn ọkàn tó lágbára.