Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ‘Ẹ Máa Ní Sùúrù’! ti Ọdún 2023
Friday
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ ọjọ́ Friday dá lórí 1 Kọ́ríńtì 13:4—“Ìfẹ́ máa ń ní sùúrù.”
Saturday
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ ọjọ́ Saturday dá lórí 1 Tẹsalóníkà 5:14—“Ẹ máa mú sùúrù fún gbogbo èèyàn.”
Sunday
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ ọjọ́ Sunday dá lórí Àìsáyà 30:18—“Jèhófà ń fi sùúrù dúró láti ṣojúure sí yín.”
Ohun tá a fẹ́ kí àwọn tó wá sí àpéjọ yìí mọ̀
Ohun tá a fẹ́ kí àwọn tó wá sí àpéjọ yìí mọ̀.
O Tún Lè Wo
Nípa Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà
Wá sí àpéjọ ọdún 2026—“Ayọ̀ Ayérayé”
A fẹ́ kó o wá sí àpéjọ ọlọ́jọ́ mẹ́ta táwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà fẹ́ ṣe lọ́dún yìí.
ÀPÉJỌ
A Fẹ́ Kó O Wá Sí Àpéjọ ‘Ẹ Máa Ní Sùúrù’! ti Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti Ọdún 2023
A pè ẹ́ wá sí àpéjọ ọlọ́jọ́ mẹ́ta tí àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ṣe.
ÀPÉJỌ
Ìtọ́wò Fídíò: “Fi Ọ̀nà Rẹ Lé Jèhófà Lọ́wọ́”
Wo fídíò yìí kó o lè mọ báwọn ìṣòro tuntun tá à ń ní ṣe lè mú ká pinnu pé a máa túbọ̀ gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà.

