Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ ló wà níbí. Inú rẹ̀ ni wàá ti rí ìtòlẹ́sẹẹsẹ ìpàdé, Bíbélì kíkà ọ̀sọ̀ọ̀sẹ̀ àti ohun tí àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà fi máa ń kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ nínú ọ̀kan lára àwọn ìpàdé tá a máa ń ṣe lọ́sọ̀ọ̀sẹ̀.