Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa máa ń pèsè ìsọfúnni tí àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ń lò ní àwọn ìpàdé yìí: Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ, Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run àti Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn.

Àkíyèsí: Àwọn àpilẹ̀kọ tí a tẹ̀ jáde ní àwọn èdè kan lè yàtọ̀ sí èyí tó wà lórí íńtánẹ́ẹ̀tì.