Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè Ayọ̀ Ayérayé ti Ọdún 2026
Friday
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ ọjọ́ Friday dá lórí Mátíù 5:3—“Aláyọ̀ ni àwọn tó ń wá ìtọ́sọ́nà Ọlọ́run.”
Saturday
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ ọjọ́ Saturday dá lórí Ìṣe 20:35—“Ayọ̀ púpọ̀ wà nínú fífúnni ju èyí tó wà nínú rírígbà lọ.”
Sunday
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ ọjọ́ Sunday dá lórí Mátíù 13:16—“Aláyọ̀ ni ojú yín torí wọ́n rí àti etí yín torí wọ́n gbọ́.”
Ohun Tá A Fẹ́ Kí Àwọn Tó Wá Sí Àpéjọ Yìí Mọ̀
Ohun tá a fẹ́ kí àwọn tó wá sí àpéjọ yìí mọ̀.
O Tún Lè Wo
Nípa Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà
Wá sí àpéjọ ọdún 2026—“Ayọ̀ Ayérayé”
A fẹ́ kó o wá sí àpéjọ ọlọ́jọ́ mẹ́ta táwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà fẹ́ ṣe lọ́dún yìí.
ÀPÉJỌ
A Fẹ́ Kó O Wá sí Àpéjọ “Ayọ̀ Ayérayé” ti Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti Ọdún 2026
A rọ̀ ẹ́ pé kó o wá sí Àpéjọ “Ayọ̀ Ayérayé” tá a máa ṣe lọ́dún 2026. Níbi àpéjọ yìí, wàá mọ bí wàá ṣe túbọ̀ sún mọ́ Ẹlẹ̀dàá rẹ, kó o lè ní ayọ̀ ayérayé.
ÀPÉJỌ
Ìtọ́wò Fídíò Ìtàn Bíbélì: Ìhìn Rere Látọ̀dọ̀ Jésù: Abala 4, 5 àti 6
Kí ló mú kó wu àwọn èèyàn láti gbọ́ ọ̀rọ̀ Jésù, kí làwọn kan sì ṣe nígbà tí ọ̀rọ̀ ẹ̀ ta ko àwọn àṣà àtọwọ́dọ́wọ́ wọn?

