Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè Ìjọsìn Mímọ́ Ọdún 2025
Friday
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ ọjọ́ Friday dá lórí Mátíù 4:10—“Jèhófà Ọlọ́run rẹ ni o gbọ́dọ̀ jọ́sìn.”
Saturday
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ ọjọ́ Saturday dá lórí Jòhánù 2:17—“Ìtara ilé rẹ máa gbà mí lọ́kàn.”
Sunday
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ ọjọ́ Sunday dá lórí Jòhánù 4:23—“Jọ́sìn Baba ní ẹ̀mí àti òtítọ́.”
Ohun Tá A Fẹ́ Kí Àwọn Tó Wá Sí Àpéjọ Yìí Mọ̀
Ohun tá a fẹ́ kí àwọn tó wá sí àpéjọ yìí mọ̀.
O Tún Lè Wo
Nípa Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà
Wá sí àpéjọ ọdún 2026—“Ayọ̀ Ayérayé”
A fẹ́ kó o wá sí àpéjọ ọlọ́jọ́ mẹ́ta táwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà fẹ́ ṣe lọ́dún yìí.
ÀPÉJỌ
A Fẹ́ Kó O Wá sí Àpéjọ “Ìjọsìn Mímọ́” ti Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti Ọdún 2025
Kí ni Jésù sọ nípa ìjọsìn mímọ́?
ÀPÉJỌ
Ìtọ́wò Fídíò Ìtàn Bíbélì: Ìhìn Rere Látọ̀dọ̀ Jésù: Abala 2 àti 3
Ní báyìí tí Jésù ti dàgbà, ó bẹ̀rẹ̀ sí í kó àwọn ọmọ ẹ̀yìn jọ, àwọn èèyàn sì ń ta kò ó.

