Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà
Kẹ́kọ̀ọ́ lára àwọn ọ̀rẹ́ Jèhófà tí Bíbélì sọ̀rọ̀ wọn!
Méfíbóṣétì
Táwọn èèyàn bá hùwà àìdáa sí ẹ, kí ló lè jẹ́ kó o máa láyọ̀ bíi Méfíbóṣétì?
Jósẹ́fù
Àwọn ẹ̀gbọ́n Jósẹ́fù ṣe ohun tó burú gan-an sí i. Àmọ́ kí ni Jósẹ́fù ṣe?
Jóṣúà àti Kélẹ́bù
Kí ló mú kí Jóṣúà àti Kélẹ́bù nígboyà nígbà tẹ́rù ń ba àwọn tó kù?
Ábígẹ́lì
Kí ni Ábígẹ́lì ṣe kí ọ̀rẹ́ kan má bàa hùwà burúkú kó sì máa ṣe ohun tó dáa?
Dèbórà
Kí lo lè ṣe kó o lè nígboyà bíi ti Dèbórà?
Ébẹ́lì
Kí lo lè kọ́ lára Ébẹ́lì tó o bá fẹ́ nígbàgbọ́ nínú Jèhófà?
Jeremáyà
Kí lo rí kọ́ lára Jeremáyà tó jẹ́ ọ̀rẹ́ Jèhófà tó bá di pé kó o ní ìgboyà?
Hananáyà, Míṣáẹ́lì àti Asaráyà
Ṣé wàá máa ṣègbọràn bíi ti Hananáyà, Míṣáẹ́lì àti Asaráyà tí wọ́n jẹ́ ọ̀rẹ́ Jèhófà?
Máà bínú, kò sóhun tó jọ ohun tó ò ń wá.

