Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

APRIL 21, 2017
OHUN TUNTUN

Ìpinnu tí Ilé Ẹjọ́ Gíga Jù Lọ Lórílẹ̀-èdè Rọ́ṣíà Ṣe​—Fídíò

Ìpinnu tí Ilé Ẹjọ́ Gíga Jù Lọ Lórílẹ̀-èdè Rọ́ṣíà Ṣe​—Fídíò

Ní April 20, 2017, Ilé Ẹjọ́ Gíga Jù Lọ lórílẹ̀-èdè Rọ́ṣíà dá àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà lẹ́bi, wọ́n fọwọ́ sí ohun tí Ilé Iṣẹ́ Ètò Ìdájọ́ sọ pé kí wọ́n ti Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Tó Ń Bójú Tó Iṣẹ́ Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà pa. Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa pe ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn lórí ọ̀rọ̀ yìí.

Fídíò kan ti wà lórí Tẹlifíṣọ̀n JW tó máa jẹ́ kó o mọ̀ sí i nípa ohun tó ṣẹlẹ̀ nílé ẹjọ́ àti ohun tí Ìgbìmọ̀ Olùdarí Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà sọ nípa ohun tó ṣẹlẹ̀ yìí.