Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

OCTOBER 28, 2016
OHUN TUNTUN

O Ti Lè Forúkọ Sílẹ̀ Pé O Fẹ́ Wá Wo Ọ́fíìsì Wa

O Ti Lè Forúkọ Sílẹ̀ Pé O Fẹ́ Wá Wo Ọ́fíìsì Wa

O ti lè forúkọ sílẹ̀ báyìí lórí ìkànnì pé o fẹ́ wá wo àwọn ọ́fíìsì wa tó wà ní ìpínlẹ̀ New York. Lára àwọn ọ́fíìsì wa tó o lè wá wò ní oríléeṣẹ́ wa ní Warwick, Ibùdó Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ ti Watchtower tó wà ní Patterson àti ẹ̀ka ọ́fíìsì orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà tó wà ní Wallkill.

Ṣètò bó o ṣe fẹ́ wá wo àwọn ọ́fíìsì wa lórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.