FEBRUARY 12, 2019
OHUN TUNTUN
Fídíò Ti Wà Nínú Ìwé Ìròyìn Ayọ̀ Tó Wà Lórí Ẹ̀rọ
Ìwé Ìròyìn Ayọ̀ Látọ̀dọ̀ Ọlọ́run! tó wà lórí ìkànnì jw.org/yo àti lórí ètò ìṣiṣẹ́ JW Library ti ní àwọn fídíò láfikún sí ìwé náà. Tó o bá ti wa ìwé Ìròyìn Ayọ̀ jáde sórí JW Library ẹ, lọ sí PUBLICATIONS > PENDING UPDATES kó o lè wa èyí tó ṣẹ̀ṣẹ̀ dé tó ní fídíò jáde. Tó o bá fẹ́ kó o lè máa wo àwọn fídíò náà láwọn ìgbà tí kò sí íńtánẹ̀ẹ̀tì, ṣí ìwé Ìròyìn Ayọ̀ lórí JW Library, lẹ́yìn náà tẹ bọ́tìnnì Download Media tó wà lókè lápa ọ̀tún ẹ̀rọ rẹ.

