JULY 24, 2018
OHUN TUNTUN
Bíbélì Àtẹ́tísí—Ìwé Jòhánù Kìíní Ti Wà Lórí Ìkànnì
A ti ka ìwé Jòhánù Kìíní sórí ẹ̀rọ látinú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun tá a tún ṣe, ó sì ti wà lórí ìkànnì jw.org.
Tẹ́tí sí ìwé Jòhánù Kìíní.