Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

May 16, 2017
OHUN TUNTUN

Bá A Ṣe Lè Fi Owó Ṣètọrẹ fún Àwọn Àpéjọ Wa

Bá A Ṣe Lè Fi Owó Ṣètọrẹ fún Àwọn Àpéjọ Wa

Bí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ fi owó ṣètọrẹ fún àwọn àpéjọ tí àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ń ṣe lọ́dọọdún, àǹfààní ti wà fún àwọn orílẹ̀-èdè kan láti ṣe bẹ́ẹ̀ báyìí látorí íńtánẹ́ẹ̀tì. Tó o bá fẹ́ fowó ṣètọrẹ, lọ wo abala tá a pè ní Bó O Ṣe Lè Fi Ọrẹ Ti Iṣẹ́ Tá À Ń Ṣe Kárí Ayé Lẹ́yìn.