FEBRUARY 5, 2016
OHUN TUNTUN
Kọrin sí Jèhófà—Orin 146 sí 150 Ti Wà Lórí Ìkànnì Wa
Orin tuntun márùn-ún látinú ọ̀wọ́ Kọrin sí Jèhófà ló ti wà lórí ìkànnì jw.org/yo.
146—“Èmi Lẹ Ṣe É Fún”
147—“Àkànṣe Dúkìá”
148—“O Fún Wa Ní Ọmọ Rẹ Kan Ṣoṣo”
149—“A Dúpẹ́ fún Ìràpadà”
150—“Wá Wọn Lọ”

