Yorùbá
Abala Tuntun​—Látinú Àpamọ́ Wa
/assets/ct/28ada02fb0/images/syn_placeholder_sqr.png

SEPTEMBER 30, 2019
OHUN TUNTUN

Abala Tuntun​—Látinú Àpamọ́ Wa

Abala Tuntun​—Látinú Àpamọ́ Wa

Abala tuntun kan ti wà lórí ìkànnì jw.org àti ètò ìṣiṣẹ́ JW Library báyìí tá à ń pè ní “Látinú Àpamọ́ Wa.” Abala yìí wà lábẹ́ “Ìtẹ̀jáde” lórí ìkànnì àti lórí JW Library. Nínú abala yìí, o máa rí àwọn àpilẹ̀kọ tó ń sọ ìtàn àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà lóde òní.

Lọ sí abala “Látinú Àpamọ́ Wa.