Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

MAY 11, 2018
ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìfẹ́ Sún Wọn Ṣiṣẹ́​—Ìrànwọ́ Nígbà Àjálù Tó Wáyé Láwọn Erékùṣù Caribbean

Ìfẹ́ Sún Wọn Ṣiṣẹ́​—Ìrànwọ́ Nígbà Àjálù Tó Wáyé Láwọn Erékùṣù Caribbean

Nínú fídíò yìí, ẹ máa rí ìsọfúnni lọ́ọ́lọ́ọ́ nípa iṣẹ́ ìrànwọ́ tó ń lọ lọ́wọ́ lẹ́yìn tí ìjì líle Irma àti Maria jà láwọn ilẹ̀ tó wà lábẹ́ àbójútó ẹ̀ka ọ́fíìsì Barbados, Faransé àti Amẹ́ríkà. Ẹ máa gbọ́ nípa iṣẹ́ àṣekára tí ọ̀pọ̀ àwọn tó yọ̀ǹda ara wọn ṣe láti ran àwọn ará wọn lọ́kùnrin lóbìnrin lọ́wọ́, ẹ̀ẹ́ sì tún gbọ́ àlàyé ṣókí nípa ìbẹ̀wò tí Arákùnrin Mark Sanderson tó jẹ́ ara Ìgbìmọ̀ Olùdarí ṣe pẹ̀lú Gary Breaux tó jẹ́ olùrànlọ́wọ́ Ìgbìmọ̀ Iṣẹ́ Ìsìn.