Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

ÌRÒYÌN

Philippines

APRIL 26, 2017

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Tún Àwọn Ilé Kọ́ Lẹ́yìn Tí Ìjì Super Typhoon Nock-Ten

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń ṣètò ìrànwọ́, wọ́n ń tún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ilé ṣe lẹ́yìn tí ìjì runlérùnnà kan jà lórílẹ̀-èdè Philippines ní ìparí ọdún 2016.

JANUARY 21, 2015

Lẹ́yìn Ọdún Kan Tí Ìjì Líle Jà ní Ìlú Haiyan, Àwọn Tí Ìjì Ba Ilé Wọn Jé Rílé Tuntun Kó Sí

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà bẹ̀rẹ̀ àtúnkọ́ ilé tó tó [750] lẹ́yìn ìjì líle tó ṣẹlẹ̀ ní ìlú Haiyan.