Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

MAY 22, 2017
ORÍLẸ̀-ÈDÈ AMẸ́RÍKÀ

Wọ́n Wá Wo Oríléeṣẹ́ Wa ní Warwick: A Fọ̀rọ̀ Wá William Hoppe Lẹ́nu Wò

Wọ́n Wá Wo Oríléeṣẹ́ Wa ní Warwick: A Fọ̀rọ̀ Wá William Hoppe Lẹ́nu Wò

Ẹnjiníà kan tó ṣojú fún Ìlú Warwick wá ṣe àyẹ̀wò nígbà táwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń kọ́ oríléeṣẹ́ wa tuntun. Ó sọ àwọn ohun tó rí nípa ilé tá a kọ́ yìí.