Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

MAY 22, 2017
ORÍLẸ̀-ÈDÈ AMẸ́RÍKÀ

Wọ́n Wá Wo Oríléeṣẹ́ Wa ní Warwick: A Fọ̀rọ̀ Wá Ingrid Magar Lẹ́nu Wò

Wọ́n Wá Wo Oríléeṣẹ́ Wa ní Warwick: A Fọ̀rọ̀ Wá Ingrid Magar Lẹ́nu Wò

Obìnrin kan tó ń gbé nítòsí, ní ọgbà Tuxedo Park ní New York, sọ àwọn ohun tó rí nípa oríléeṣẹ́ tuntun táwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà kọ́ sílùú Warwick, ní New York.