Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

ÌRÒYÌN

Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà

MAY 22, 2017

Wọ́n Wá Wo Oríléeṣẹ́ Wa ní Warwick: A Fọ̀rọ̀ Wá William Hoppe Lẹ́nu Wò

‘Gbogbo nǹkan ni wọ́n ń ṣe nigínnigín. Mi ò tíì rí àwọn òṣìṣẹ́ ìkọ́lé tó fọwọ́ pàtàkì mú ọ̀rọ̀ ẹ̀mí bíi ti àwọn tá a jọ ṣiṣẹ́ ní Warwick yìí.’

MAY 22, 2017

Wọ́n Wá Wo Oríléeṣẹ́ Wa ní Warwick: A Fọ̀rọ̀ Wá Ingrid Magar Lẹ́nu Wò

‘Inú mi dùn sí ohun tí ibí yìí dà. Ibí yìí rẹwà gan-an, ẹ sì ti wá bù kún ẹwà ẹ̀. Inú wa dùn gan-an pé ẹ kó wá sí àdúgbò wa.’

MAY 22, 2017

Àwọn Aráàlú Sọ Ohun Tó Dáa Nípa Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Nígbà Tí Wọ́n Wá Wo Oríléeṣẹ́ Wa Tuntun

Àwọn tó wá ní ọ̀sẹ̀ kejì pọ̀ ju ti ọ̀sẹ̀ àkọ́kọ́, àwọn aládùúgbò sì sọ ohun tí wọ́n rí nípa ilé tuntun náà.