Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

ÌRÒYÌN

Mexico

NOVEMBER 4, 2015

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Gba Àmì Ẹ̀yẹ Nítorí Iṣẹ́ Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì tí À Ń Ṣe Láwọn Ọgbà Ẹ̀wọ̀n Orílẹ̀-èdè Mẹ́síkò

Àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba dúpẹ́ lọ́wọ́ àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà fún ìsapá wa láti kọ́ àwọn ẹlẹ́wọ̀n lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ní ìpínlẹ̀ Baja California.

MAY 22, 2015

Wọ́n Pe Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Sí Ayẹyẹ Tó Fa Kíki Tàwọn Òǹṣèwé Nílùú Tó Ń Sọ Èdè Sípáníìṣì

Wọ́n pàtẹ oríṣiríṣi ìwé tí wọ́n ṣe jákèjádò ayé níbi ayẹyẹ ìpàtẹ ìwé kan nílùú Guadalajara títí kan ìtẹ̀jáde táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ṣe.

APRIL 24, 2015

A Mú Ìwé Mímọ́ Kristẹni Lédè Gíríìkì ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun Jáde Lédè Tzotzil Lórílẹ̀-èdè Mẹ́síkò

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà mú Ìwé Mímọ́ Kristẹni Lédè Gíríìkì (“Májẹ̀mú Tuntun”) jáde lédè Tzotzil. Àwọn ẹ̀yà Máyà tó ń gbé ní àgbègbè Chiapas ló ń sọ èdè yìí jù.