Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

ÌRÒYÌN

Kazakhstan

MAY 17, 2017

Àwọn Aláṣẹ ní Kazakhstan Fi Ẹlẹ́rìí Jèhófà Tó Ń Ṣàìsàn Sẹ́wọ̀n, Wọ́n sì Fòfin Dè é Pé Kò Gbọ́dọ̀ Jọ́sìn

Teymur Akhmedov ti níyàwó, ó sì ti bímọ mẹ́ta. Àwọn aláṣẹ rán an lọ sẹ́wọ̀n ọdún márùn-ún torí pé ó ń kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì, bẹ́ẹ̀ sì rèé, ìrọwọ́rọsẹ̀ ló ń ṣe é.

JANUARY 27, 2015

Bíbélì Kazakh Tuntun Tí Wọ́n Mú Jáde Ní Àpéjọ àti Ètò Rírìn Yíká Ọgbà

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà mú Bíbélì Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun jáde lédè Kazakh ní àpéjọ tí wọ́n ṣe ní ìlú Almaty, lórílẹ̀-èdè Kazakhstan