Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Guatemala

May 6, 2015

Àwọn Iléèwé Ní Guatemala Fẹ́ Yanjú Ìwà Jàgídíjàgan Àwọn Ọ̀dọ́; Wọ́n Béèrè Ìwé Lọ́dọ̀ Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Àwọn iléèwé lórílẹ̀-èdè Guatemala béèrè fún ẹgbẹẹgbẹ̀rún ìwé lédè Sípáníìṣì àti Quiché. Wọ́n ń lo àwọn ìwé náà láti kọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní èdè Quiché, wọ́n sì tún ń lò ó láti kọ́ ní ìwà rere.