Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

ÌRÒYÌN

Finland

NOVEMBER 24, 2017

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ti Pa dà Sẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù Níbi Térò Pọ̀ Sí Ní Turku lórílẹ̀-èdè Finland

Àwọn afẹ̀míṣòfò pa èèyàn ní ìlú Turku lórílẹ̀-èdè Finland ní August 18, 2017. Àmọ́ ọjọ́ díẹ̀ lẹ́yìn ìṣẹ̀lẹ̀ yẹn, inú àwọn òṣìṣẹ́ ìlú dùn gan-an láti rí i pé àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti pa dà sẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù ní gbàgede ọjà yẹn.

SEPTEMBER 4, 2017

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Tu Àwọn Èèyàn Nínú lẹ́yìn Ìpànìyàn tó wáyé nílùú Turku, lórílẹ̀-èdè Finland

Ètò ìrànwọ́ tí ẹ̀ka ọ́fíìsì ṣe lẹ́yìn ìṣẹ̀lẹ̀ yẹn tu àwọn èèyàn nínú títí kan àwọn tí kì í ṣe Ẹlẹ́rìí Jèhófà, ó sì fi wọn lọ́kàn balẹ̀.