Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

ÌRÒYÌN

Ìròyìn Kárí Ayé

MAY 16, 2017

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ti Bẹ̀rẹ̀ Àpéjọ Àgbègbè Tọdún Yìí

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń pe gbogbo èèyàn wá sí àpéjọ ọlọ́jọ́ mẹ́ta tá a máa bẹ̀rẹ̀ láti May 19, 2017. Àkòrí rẹ̀ ni “Má Sọ̀rètí Nù!”

MARCH 30, 2017

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ń Palẹ̀ Mọ́ fún Àwọn Ìpàdé Pàtàkì tí Wọ́n Fẹ́ Ṣe Lọ́dún 2017

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà kárí ayé ti ń ṣètò láti jọ pé àwọn èèyàn wá síbi àwọn ìpàdé pàtàkì tí wọ́n máa ń ṣe lọ́dọọdún. Ìrántí Ikú Kristi ni wọ́n máa kọ́kọ́ ṣe.

MAY 4, 2016

Ìdúróṣinṣin ni Àpéjọ Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ọdún 2016 Dá Lé

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ṣe Àpéjọ Àgbègbè tí àkòrí rẹ̀ sọ pé “Jẹ́ Adúróṣinṣin sí Jèhófà!” kárí ayé. Gbogbo èèyàn la pè sí àpèjọ ọlọ́jọ́-mẹ́ta yìí, ọ̀fẹ́ sì ni.