“Nǹkan burúkú gbáà ni bí wọ́n ṣe lo òfin tí kò tọ́ yìí láti fi ṣe ohun tó burú jáì.”

Agbẹjọ́rò tó ń jà fún ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn níbi gbogbo lágbàáyé, ó tún ń ṣojú fún ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì ní ìlú Venice