Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

APRIL 5, 2017
RUSSIA

Lyudmila Alekseyeva

Lyudmila Alekseyeva

“Wọ́n ń mọ̀ọ́mọ̀ fúngun mọ́ àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ni; lójú tèmi, ìwà ọ̀daràn nìyẹn.”

Alága Ẹgbẹ́ Moscow Helsinki Group, Ara Ìgbìmọ̀ Tó Ń Bá Ààrẹ Ṣiṣẹ́ Lórí Ọ̀rọ̀ Aráàlú àti Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn ní Rọ́ṣíà