Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

APRIL 3, 2017
RUSSIA

Dr. Massimo Introvigne

Dr. Massimo Introvigne

“Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà kì í ṣe oníwà ipá rárá. Àwọn gan-an làwọn èèyàn máa ń hùwà ipá sí.”

Ọ̀mọ̀wé Nípa Ohun Tó Ń Lọ Láwùjọ àti Aṣojú Tẹ́lẹ̀ fún Àjọ OSCE Lórí Ọ̀rọ̀ Gbígbógun Ti Kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà