Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ọ̀RÀN ẸJỌ́ KÁRÍ AYÉ

Wọ́n Fi Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Sẹ́wọ̀n Torí Ohun tí Wọ́n Gbà Gbọ́​—Ibì Kọ̀ọ̀kan

Wọ́n Fi Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Sẹ́wọ̀n Torí Ohun tí Wọ́n Gbà Gbọ́​—Ibì Kọ̀ọ̀kan

Gbogbo àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó wà lẹ́wọ̀n ní July 2017

ORÍLẸ̀-ÈDÈ

IYE TÓ WÀ LẸ́WỌ̀N

ÌDÍ

Eritrea

53

  • Ẹ̀rí ọkàn ò gbà wọ́n láyè láti ṣiṣẹ́ ológun

  • Wọ́n ń jọ́sìn Ọlọ́run

  • Wọn ò sọ ohun tó fà á

 

Kazakhstan

1

  • Ó ń jọ́sìn Ọlọ́run

 

Rọ́ṣíà

1

  • Ó ń jọ́sìn Ọlọ́run

 

Singapore

9

  • Ẹ̀rí ọkàn ò gbà wọ́n láyè láti ṣiṣẹ́ ológun

 

South Korea

401

  • Ẹ̀rí ọkàn ò gbà wọ́n láyè láti ṣiṣẹ́ ológun

 

Turkmenistan

1

  • Wọ́n ń jọ́sìn Ọlọ́run

 

Àròpọ̀

466

 

Àpilẹ̀kọ 18 nínú àdéhùn International Covenant on Civil and Political Rights sọ pé ara ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn ni “ẹ̀tọ́ láti ní èrò tó wuni, láti ṣe ohun tí ẹ̀rí ọkàn ẹni bá gbà láyè àti ẹ̀sìn tó wuni.” * Láwọn ilẹ̀ kan, wọ́n máa ń fi àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó bá ṣe ohun tí wọ́n lẹ́tọ̀ọ́ sí yìí sẹ́wọ̀n, wọ́n tiẹ̀ máa ń hùwà ìkà sí wọn. Géńdé ọkùnrin ni ọ̀pọ̀ lára àwọn tí wọ́n fi sẹ́wọ̀n, torí pé ẹ̀rí ọkàn wọn ò gbà wọ́n láyè láti ṣe iṣẹ́ ológun. Torí pé àwọn míì sì ń ṣe ohun tí wọ́n gbà gbọ́ ló jẹ́ kí wọ́n fi wọ́n sẹ́wọ̀n.

^ ìpínrọ̀ 29 Tún wo ìwé United Nations Universal Declaration of Human Rights, Àpilẹ̀kọ18, àti European Convention on Human Rights, Àpilẹ̀kọ 9.