Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ìròyìn Kárí Ayé

 

2019-01-15

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Àwọn Ilé Ẹjọ́ ní Czech Republic àti Slovakia Dá Àwọn Ará Wa Láre

Láti May 1, 2017 sí January 8, 2018, àwọn ilé ẹjọ́ dá àwọn ará wa láre lẹ́yìn tí ilé ẹjọ́ ti fẹ̀sùn ọ̀daràn kàn wọ́n lọ́pọ̀ ọdún sẹ́yìn torí pé ẹ̀rí ọkàn ò jẹ́ kí wọ́n ṣiṣẹ́ ológun tàbí pé wọ́n ń ṣiṣẹ́ ìwàásù.

2019-01-15

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ilé Ẹjọ́ ní Slovakia Dá Martin Boor Láre Lẹ́yìn Àádọ́rùn-ún Ọdún Tí Wọ́n Ti Sọ Pé Ó Jẹ̀bi

Ilé ẹjọ́ kan ní Slovakia dá Martin Boor láre, ẹni tí wọ́n ti fẹ̀sùn ọ̀daràn kàn tẹ́lẹ̀ torí pé ẹ̀rí ọkàn ẹ̀ ò jẹ́ kó ṣiṣẹ́ ológun.

2018-09-17

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìfẹ́ Sún Wọn Ṣiṣẹ́​—Ìrànwọ́ Nígbà Àjálù Tó Wáyé Láwọn Erékùṣù Caribbean

Fídíò yìí jẹ́ ká rí ìsọfúnni lọ́ọ́lọ́ọ́ nípa iṣẹ́ àṣekára táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó yọ̀ǹda ara wọn ṣe lẹ́yìn tí ìjì líle Irma àti Maria jà.

2018-07-09

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Àpéjọ Àgbègbè Tí Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Máa Ń Ṣe Lọ́dọọdún Máa Bẹ̀rẹ̀ ní May 2018

Kó tó dìgbà yẹn, kárí ayé làwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti máa ké sí gbogbo èèyàn pé kí wọ́n wá síbi àpéjọ náà lọ́fẹ̀ẹ́.

2018-05-16

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé Fi Hàn Pé Àwọn Wà Níṣọ̀kan Nígbà Tí Wọ́n Ń Kọ Lẹ́tà Sáwọn Aláṣẹ ní Rọ́ṣíà

Lẹ́tà táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà kọ sáwọn aláṣẹ ní Rọ́ṣíà láti ti àwọn ará wọn ní Rọ́ṣíà lẹ́yìn fi hàn pé ìṣọ̀kan wà láàárín wọn kárí ayé, èyí sì wúni lórí.

2018-05-16

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Túbọ̀ Ń Ṣètò Ìrànwọ́ Lẹ́yìn Ìjì Líle Tó Jà

Àwọn ẹ̀ka ọ́fíìsì àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà sọ̀rọ̀ nípa ìrànwọ́ tí wọ́n ń ṣe fáwọn tí ìjì líle Hurricane Irma àti Hurricane Maria ṣèpalára fún àti bí wọ́n ṣe ń fi ọ̀rọ̀ Ọlọ́run tù wọ́n nínú.

2018-04-10

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ohun Tó Ṣẹlẹ̀ Lẹ́yìn Ìjì Líle Hurricane Irma

Ìròyìn láti ẹ̀ka ọ́fíìsì wa ní in Barbados, Dominican Republic, France, àti Amẹ́ríkà.

2017-07-04

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ti Bẹ̀rẹ̀ Àpéjọ Àgbègbè Tọdún Yìí

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń pe gbogbo èèyàn wá sí àpéjọ ọlọ́jọ́ mẹ́ta tá a máa bẹ̀rẹ̀ láti May 19, 2017. Àkòrí rẹ̀ ni “Má Sọ̀rètí Nù!”

2017-04-20

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ń Palẹ̀ Mọ́ fún Àwọn Ìpàdé Pàtàkì tí Wọ́n Fẹ́ Ṣe Lọ́dún 2017

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà kárí ayé ti ń ṣètò láti jọ pé àwọn èèyàn wá síbi àwọn ìpàdé pàtàkì tí wọ́n máa ń ṣe lọ́dọọdún. Ìrántí Ikú Kristi ni wọ́n máa kọ́kọ́ ṣe.